Web Analytics Made Easy - Statcounter

See also ebooksgratis.com: no banners, no cookies, totally FREE.

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Lítírésò - Wikipedia

Lítírésò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Old book bindings at the Merton College library.
Old book bindings at the Merton College library.

Litireso

OHUN TÍ LÍTÍRÉSÒ JÉ

Eléyìí náà kò sàì ní orírun tirè láti inú èdè Látìn “LITERE” Èyí ni àwon géésì yá wo inú èdè won tí wón ń pè ni lete rature” Ìtumò tí a fún lítírésò máa ń yípadà láti òdò èyà ènìyàn kan sí èkejì láti ìgbà dé ìgbà. Lítírésò kò dúró sójú kan. Babalolá (1986), sàpèjúwe lítírésò pé:

“Àkójopò ìjìnlè òrò ní èdè kan tàbí òmíràn tó jásí ewì, ìtàn àló, ìyànjú, eré onítàn, ìròyìn àti eré akónilógbón lórí ìtàgé”

Tí a bá wo òde òní, ìtumò tí a fún lítírésò tún yàtò, fún àpeere a máa ń sàkíyèsí ìlò èdè tí wón fi ko ìwé kan yàtò sí èyí, a tún ka lítírésò kùn isé ònkòwé alátinúdá tàbí isé tó ní í se pèlú òrò ìlò ojú inú gégé bí ewì, ìtàn àròko àti eré oníse. A ó sì rí i pe awé tàbí èyà lítírésò tí a mènubà wònyí kó púpò nínú ìmò ìgbé èdá láwújo (folklore) mó ara, yálà, a ko, ó sílè, a rò ó so tàbí a se é léré yàtò fún àwon àkoó lè isé owó. Lítírésò tún jé irúfé àkoólè tó ní àbùdá èmí gígùn, ó máa ń fi ìsèse àti àsà àgbáríjo àwon èèyàn kan hàn. Àwon míràn tó tún sòrò lórí lítírésò ni àwon omo léyìn Mark: Àwon Marxist (1977) yìí gbà pé:

“Scrutiny of the literature could not be realize without the society”

Èyí ni pé:

“Lítírésò kò lè se é dá yèwò láìwo àwùjo tí a ko ó fún”

Kí ònkòwé kan tó lè se isé rè ní àseyanjú, irúfé onkòwé náà gbódò ni àtinúdá àtinúdá yìí pèlú ohun gan-an tí ó ń selè láwùjo ni yóò wá so di òkan nínú isé rè. Lara àwon tí ó sisé lórí ìlànà Marx yìí ni: Trosky ara Russia, Lucas àti Goldmann. Daviguand (1960) ni tíórì so pé

“Literature enumerate the future thought of an individual (Human being)

Èyí ni pé:

“Lítírésò wà fún láti máa so èrò okàn ènìyàn jáde nípa ojó iwájú”

Nípa yíye lítírésò wò, à ní láti wo èhun ìpìlè ìtumò, èyí ni wíwo gbogbo nnkan tí ó wà láwùjo yen olápapò láì dá òkan sí.




aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -