Idije Olympiki
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Idije Olympiki {tabi Olympiki} je opolopo ere idaraya ti won sele ni igba ooru ati igba otutu. Won n sele lekan larin odun merin. Titi di 1992, ninu odun kanna ni won n sele. Lat'igbana won ti ya won soto pelu odun meji.
Awon idije olympiki (ede Greeki: Ολυμπιακοί Αγώνες; Olympiakoi Agones) akoko waye ni odun 776 BC ni ilu Olympia ni ile Greesi.