Benin
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́
République du Bénin
Republic of Benin
Ile Olominira Orile-ede Benin |
||||||
---|---|---|---|---|---|---|
|
||||||
Motto: "Fraternité, Justice, Travail" (Faranse) "Fellowship, Justice, Labour" |
||||||
Orin orile-ede: L'Aube Nouvelle (French) The Dawn of a New Day |
||||||
Oluilu | Porto Novo1 |
|||||
Ilu totobijulo | Cotonou | |||||
Èdè lìlò fún isẹ́ | Faranse | |||||
Demonym | Beninese; Beninois | |||||
Government | Multiparty democracy | |||||
- | President | Yayi Boni | ||||
Independence | from France | |||||
- | Date | August 1 1960 | ||||
Area | ||||||
- | Total | 112,622 km² (101st) 43,483 sq mi |
||||
- | Omi (%) | 1.8 | ||||
Ìpọ̀síènìyàn | ||||||
- | July 2005 estimate | 8,439,0002 (89th) | ||||
- | 2002 census | 6,769,914 | ||||
- | Density | 75/km² (118th3) 194/sq mi |
||||
GDP (PPP) | 2005 estimate | |||||
- | Total | $8.75 billion (140th) | ||||
- | Per capita | $1,176 (166th) | ||||
Gini (2003) | 36.5 (medium) | |||||
HDI (2007) | ▲ 0.437 (low) (163rd) | |||||
Currency | CFA franc (XOF ) |
|||||
Time zone | WAT (UTC+1) | |||||
- | Summer (DST) | not observed (UTC+1) | ||||
Internet TLD | .bj | |||||
Calling code | +229 | |||||
1 | Cotonou is the seat of government. | |||||
2 | Estimates for this country explicitly take into account the effects of excess mortality due to AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex than would otherwise be expected. | |||||
3 | Rank based on 2005 estimate. |
Orile-ede Olominira Benin je orile-ede ni Apa Ilaoorun Afrika ti a mo tele gege bi Dahomey (titi de odun 1975). O ni bode pelu Togo ni apa ilaoorun, Naijiria ni apa iwoorun, ati Burkina Faso ati Nijeri ni ariwa. Ni guusu o jasi Etiodo Benin (Bight of Benin). Botileje pe oluilu re je Porto Novo ibujoko ojoba wa ni Kotonou.
Contents |
[s'àtúnṣe] Oruko
"Benin" gege bi oruko re ko ni ohunkohun se pelu Ilẹ̀ọba Benin (tabi Benin City). Oruko re tele je Dahomey ki a to yi si Orile-ede Agbajumo Olominira Benin ni odun 1975 nitori egbe odo to wa eyun Etiodo Benin. Won mu oruko yi nitoripe ko fi s'egbe kan larin gbogbo awon eya eniyan bi adota ti won wa ni ile Benin. Dahomey je oruko iluoba Fon ti ayeijoun, nitori eyi won ro pe ko to.
[s'àtúnṣe] Ìtàn
Iluoba Dahomey je didasile lat'owo awon orisirisi eya ni Abomey. Awon akọ̀tàn ro pe boya aisi abo ti owo eru dasile ni o fa ogunlogo ero eniyan lati ko lo si Abomey, ninu awon wonyi na sini obaalade Allada je okan.
[s'àtúnṣe] Oselu
Iru iselu je ti opolopo egbe oloselu ti won yan awon asoju pelu aare abasewa nibiti Aare ile Benin, ti se Yayi Boni lowolowo bayi, je olori orile-ede ati olori ijoba. Agbara iseoba wa lowo ijoba. Agbara isofin wa lowo ijoba ati ile asofin. Ile Adajo ni ominira lowo ijoba ati asofin. Iru ona iselu lowolowo bayi bere ni 1990 pelu Ofinigbepo ile Benin ati iyipada si ti oloselu ti o tele ni odun 1991.
[s'àtúnṣe] Awon ipinle ijoba
Ile Benin je pinpin si ijoba abele mejila (French: départements), awon wonyi si tun je pinpin si ibile 77. Ni odun 1999 ni won pin awon ijoba abele mefa to wa tele si mejila.
- Alibori
- Atakora
- Atlantique
- Borgou
- Collines
- Donga
- Kouffo
- Littoral
- Mono
- Ouémé
- Plateau
- Zou