Web Analytics Made Easy - Statcounter

See also ebooksgratis.com: no banners, no cookies, totally FREE.

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Architecture - Wikipedia

Architecture

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́

AWORAN ILÉ KÍKÓ (ARCHITECTURE)

Aworan ilé kíkó ni ogbón èkó ìjìnlè fun àwòrán ilé kíkó àti àwon ìkólé míran. Bí a bá wò ó jinlè, ilé kíkó nísè pèlú bí àwòrán gbogbo àdúgbò náà yíò ti rí. Gbogbo bí àyíká àti títí kan àga tí ó wà nínu inú nlé, bí gbogbo rè yíò se je ojú ní gèse.

Àwon ògá ilé kíkó a máa gbè èrò òkàn won jade nígbà tí àwon èròjà bá pé sílè fún àpeere:- ilè tó fèè, owó, ìmò ìjìnlè atí irínsé ìgbàlódé. Eléyìí ló maá n fa kóríyá fún won isé won yíò wunnu rí pàápàá.

A lè ní ìmò nípa ilé kíkó làti ara ohun tí afi ojú rí, fi eetí gbo àti ohun tí a rò lókàn wa, làti jé kí ile kíkó wunni lópòlopò. Nígbá mìíràn, gbogbo bí olórun se dá ilé ayé gan a máa wunmi, torínà ara ònà ilé kíkó ni.

Bí a bá se ronú a maa yàtò, eléyìí mú kí isé ilè kíkó se é wò. Isé ilé kíkó máa n fi àsà àti ìse hàn nípa bí wón ti rí ní àyé àtijó. Fún àpèerè; ilè oba ààfín kábíyèsí, ojúbo sàngó, sóósì àti béèbéè lo. Irú àwon ilé bè a máa fa òpòlopò èrò je làti kó won ní àsè àti ìse ilè wa;

Isé ilé kíkó ní ònà tí a un gbà làti kó ilé. Lára ìse ilé kíkó ní; ìsírò, yíya àwòrán, ìbójútó ilé tí a ún kó lówó. Isé ilé kíkó ní pé kí a mo iye owo tí yóò ná wa láti kólé àti bí won yóò se máa gbe tàbí lo bè.

Alábòjùtó ilé-kíkó gbódò je kí ohun tí ó fé kó dára fún àpèere; iye ènìyàn tí yóò máa gbé be ikéji èwè ni pé kó ó wúlò fún ohun tí wón bá fé se ní ibè àti bí ó se wunni loju ni ìwòn tó dára.

Isé olùkólé ni pé kí ilé àti agbègbè ti jo ojú ní gbèsè, kí ó fún àwon ènìyàn ní ìfòkàn bàlè àti àlànfíá làti lè jè kí isé wón yoo, òlùkólé gbódò ni ìmò èkó “sáyènsì” àti òpolopò ìrírí ní enú isé. Ìmò èro ayára bí àsá pàápàá ti bu ewà fún ise ilé kíkó lóde òní.

IMÒRÀN OLÙKÓLÉ ÀGBÀ

Olùkólé àgbà Vitruvius lo wì pe:

(1) Àlòpé :- ilé tí abá kó gbódò dúró nílè dáradára. Kósì ní àlòpé.

(2) Ànfààní:- Ilé tí a bá kó gbódó nilari (tàbí wúlò)

(3) Ewà:- Ilé ti a bá kó gbódò re wà lójú àwon ènìyàn.

Gégé bí “Vitruvius” se so, gbogbo olùkólé gbódò sa ipá won láti tèlé gbogbo Ìmòràn wònyí.


aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -