Nọ́mbà tíkòsí
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Awon nomba ninu imo mathematiki |
---|
Basic |
Nomba adabaye |
Complex extensions |
Quaternions |
Other extensions |
Musean hypernumbers |
Other |
Nominal numbers |
Ninu imo isiro, nomba tikosi ni a mo si nomba tosoro ti alagbarameji (square) re je nomba gidi alapaosi. Rafael Bombelli ni o se itumo won ni odun 1572. Laye igbana ko seni to gba pe awon nomba ba hun wa, gege bi won se ro pe odo ati nomba apaosi ko si tabi ko wulo. Descartes ni o koko pe won be ninu iwe re isiro alawonile (La Geometrie]] lati fi re won sile