>


Web - Amazon

We provide Linux to the World


We support WINRAR [What is this] - [Download .exe file(s) for Windows]

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
SITEMAP
Audiobooks by Valerio Di Stefano: Single Download - Complete Download [TAR] [WIM] [ZIP] [RAR] - Alphabetical Download  [TAR] [WIM] [ZIP] [RAR] - Download Instructions

Make a donation: IBAN: IT36M0708677020000000008016 - BIC/SWIFT:  ICRAITRRU60 - VALERIO DI STEFANO or
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Sport - Wikipedia

Sport

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́

ERÉ ÌDÁRAYÁ (SPORT)

Eré ìdárayá jé nnkan pàtàkì tí ènìyàn omodé, àgbà-lagbà, okùnrin tàbí obìnrin máa n fi dára won lára yá tàbí fí pa owó dà, wón sì lè fi pa ìrònú ré tàbí ní àsìkò tí won kò se nnkankan. Gbogbo ènìyàn ní o mò dájú wí pé ní àsìkò tí a kò bá ní ohún kánkan ní síse ni a máa n fi eré ìdárayá bíi bóòlù aláfesègbá, bóòlù aláfowógbà àti béè béè lo pa owó dà

Eré ìdárayá jé nnkan tí ènìyàn máa n se ní ìgbà tí kò sí ohunkóhun láti se; àwon ènìyàn to máa n gbádùn láti ayébáyé. Gégé bí ó ti se rí nínú ìsiré Gíríkì. Ní òtító, àwon nnkan tàbí akítìyan bíi ilé kíkùn fi yé wa wí pé a lè to ipasè ré ìdárayá lo sí ìbèrè pèpè ìgbé ayé omo èdá ènìyàn. Òpòlopò nínú eré ìdárayá bíi bóòlù àti eré sísá tí a máa n se àjoyò lé lórí káàkiri àwon Mèdíéfà ilè Europe. Àwon eré ìdárayá bíi góòfù (Golf) àti eré esin máa n jé síse ní ààrin àwon gbajúmò ilè Éróòpù, pàápàá jùlo àwon ará Bíríténì. Ní òtító Òlímpíìkì àtijó, gbajúmò medieval, àwon ará ihò àti ìkapamó àgbè tí ó n lo láti oko kan sí èkejì, tòun ti ìtàn, wón jìnnà sí eré ìdarayé bí a se mò ní òde òní. Ìdágbàsókè eré ìdárayá ni a lè to ipasè rè lo sí ibi ìsisé àyíká àti ìdásílè ilé-èkó ti ìjoba àkókó, èyí tí ó padà jásí àwon ohun àise déédé tí àwa náà síì fojú rí. Ohun tí ó jeyo ní ibíyìí ni làti fo àwon ohun ìjà mó, kí á sì rópò àwon eré bíi sókà, bóòlù aláfowógbá àti bóòlù aláfesègbá, ní àwon èyí tí ó dúró dáradára ní àwon ilé-èkó gígá ní ìparí 1800’s àti ìbèrè 1900’s ó kéré tán ní United State. Ó jé nnkan tí ó fojú hàn wí pé ìtàn eré ìdárayá gégé bí ohun tí ó jé gbajúgbajà, kò lè sí ní ipò tí ó wà ní ìsìnyìí ní àìsí ìfé ìwé ìròyìn. Télè-télè àwon ènìyàn ko èyìn sí ìwé ìròyìn lórí eré ìdárayá. Èrò àwon ènìyàn ni wí pé abé ètò ìròyìn ni eré ìdárayá wà àti wí pé kò ní sí ìtéwógbà fún-un àti owó nínú irú nnkan béè. Ìtàn eré ìdárayá tí a mò fi hàn wí pé a máa n sìí gbó. ÌTÀN ERÉ ÌDÁRAYÁ GÓÒFÙ

Góòfù jé eré ìdárayá tí ó dára púpò tí ó sì se àgbákalè àkójopò tó dára. Nnkan tí ó síwájú eré ìdárayá góòfù tí a mò sí “Chole”, eni ti a se akósilé rè ni 1354 láti ara bókì ní wón ti fa góòfù yo. Nígbà ìkeyìn, ní odún 1421, tí àwon tí ó n bá àwon ará ilè faransé ní ilè fúlándà jà, wón fi owó ayò náà hàn wón, èyí tí àwon mú lo sí ilè won ní Scotland. Nígbà tí a ó fi rí orúndúnméjì eré ìdárayá náà ti di gbajúgbajà ní ilè Great Britain. A rí àwon oba, adarí bìnrin àti àwon onípò mííràn tí wón máa n se eré ìdárayá náà, béè ni wón sì ní òfin tí ó de eré ìdárayá náà. Ní pàtàkì jùlo, Mary, Adarí bìnrin ti ilè Scotland ni obìnrin àkókó tí ó mo góòfù ú gbá.

Tí a bá ní kí á wo ìtàn eré ìdárayá, a kò le so ìtàn náà tán nítorí wí pé ó jé nnkan tí ó gbòòrò. Eré ìdárayá ti ìsinyìí kò yàtò sí titi ogórùn-ún odún séyìn.

Ara àwon ànfààní eré ìdárayá ni wí pé ó máa n jé kí ara jí pépé, ó máa n jé kí ènìyàn ní irírí tí ó péye, ó máa n dènà wíwà láì rí nnkankan se nítorí wí pé Yorùbá bò wón ní owó tí ó bá dilè ni èsù máa n bè ní isé. Ní pàtàkì jùlo, eré ìdárayá jé ohun tí a kò le fi owó ró séyìn ní orílè èdè Nàìjíríà àti gbogbo àgbáyé ní àpapò.

ÌTÀN BÓÒLÙ ALÁGBA-JÙ-SÁPÈRÈ

Bóòlù alágba-jù-sápèrè nìkan ni eré ìdárayá tí àwon ènìyàn n wò jùlo tí a gbé jáde láti ipasè eré ìdárayá tí ó kù. Dókítà James Naismith jé enití a kò le yà kúrò níbi ìtàn bóòlù alágba-jù-sápèrè, ó gbàgbó wí pé ó jé akitiyan tí ó máa n fún àwon òdó ilè England ní agbára láti la ìgbà òjò kojá. Bóòlù alágba-jù-sápèrè àkókó wáyé ní January 20, 1892. Naismith ni ó se ìdárí ìdásílè rè n “Kansas” fún odún méfà, èyí tí ó fa titan ká eré ìdárayá náà, pèlú àjosepò YMCA, káàkiri ilé-èkó gíga pátápátá. Ní odún 1946, egbé kan tí wón n pè ní National Basketball Association di dídá sílè, tí ó se àkójo àwon omo egbé agbá bóòlù alágba-jù-sápèrè fún ìgbà àkókó nínú ìtàn. Ìtàn pípolongo eré ìdárayá nípa sè èro amóhùnmáwòrán àti èro asòrò mágbèsì jé nnkan pàtàkì tí ó mú ìgbéga nlá bá bóòlù alágba-jù-sápèrè. Eré ìdárayé àti ilé-isé amóhùnmáwòràn àti asòròmágbèsì jé nnkan tí ó ran ara won lówó nínú ìgbéga. Àkókó nínú ètò orí amóhùnmáwòrán àti asòròmágbèsì dá lé orí eré ìdárayá. Nígbà tí ìpolongo mú ìdàgbàsókè bá eré ìdárayá ní ìlànà pèlú “Museum of Broadcasting Communication”, “èyí tí ó ní èro amóhùnmáwòrán 190,000 ní odún 1948, àjosepò eré-ìdàrayá pèlú ètò ìgbé síta kò polongo dólà…sùgbón láti jé kí àwon ènìyàn máa wo èro amóhùnmáwòrán. Nígbà tí ó yá èro amóhùnmáwòrán àti ilé-iséamóhùnmáwòrán n pò lo rerere, dé ibi wí pé ní odún 1979 ESPN di àgbékalè, ní èyí tí ó kárí i ilé bí i mílíónù mérin-in ni odún 1980.


< Static Wikipedia 2008 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -

Static Wikipedia 2007 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -

Static Wikipedia 2006 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu

span style="font-weight: bold;">Our
"Network":



Project Gutenberg

href="https://gutenberg.classicistranieri.com">https://gutenberg.classicistranieri.com



Encyclopaedia Britannica 1911

href="https://encyclopaediabritannica.classicistranieri.com">https://encyclopaediabritannica.classicistranieri.com



Librivox Audiobooks

href="https://librivox.classicistranieri.com">https://librivox.classicistranieri.com



Linux Distributions

https://old.classicistranieri.com



Magnatune (MP3 Music)

href="https://magnatune.classicistranieri.com">https://magnatune.classicistranieri.com



Static Wikipedia (June 2008)

href="https://wikipedia.classicistranieri.com">https://wikipedia.classicistranieri.com



Static Wikipedia (March 2008)

href="https://wikipedia2007.classicistranieri.com/mar2008/">https://wikipedia2007.classicistranieri.com/mar2008/



Static Wikipedia (2007)

href="https://wikipedia2007.classicistranieri.com">https://wikipedia2007.classicistranieri.com



Static Wikipedia (2006)

href="https://wikipedia2006.classicistranieri.com">https://wikipedia2006.classicistranieri.com



Liber Liber

href="https://liberliber.classicistranieri.com">https://liberliber.classicistranieri.com



ZIM Files for Kiwix

https://zim.classicistranieri.com





Other Websites:



Bach - Goldberg Variations

https://www.goldbergvariations.org



Lazarillo de Tormes

https://www.lazarillodetormes.org



Madame Bovary

https://www.madamebovary.org



Il Fu Mattia Pascal

https://www.mattiapascal.it



The Voice in the Desert

https://www.thevoiceinthedesert.org



Confessione d'un amore fascista

https://www.amorefascista.it



Malinverno

https://www.malinverno.org



Debito formativo

https://www.debitoformativo.it



Adina Spire

https://www.adinaspire.com




atOptions = { 'key' : 'e601ada261982ce717a58b61cd5b0eaa', 'format' : 'iframe', 'height' : 60, 'width' : 468, 'params' : {} };

Our "Network":

Project Gutenberg
https://gutenberg.classicistranieri.com

Encyclopaedia Britannica 1911
https://encyclopaediabritannica.classicistranieri.com

Librivox Audiobooks
https://librivox.classicistranieri.com

Linux Distributions
https://old.classicistranieri.com

Magnatune (MP3 Music)
https://magnatune.classicistranieri.com

Static Wikipedia (June 2008)
https://wikipedia.classicistranieri.com

Static Wikipedia (March 2008)
https://wikipedia2007.classicistranieri.com/mar2008/

Static Wikipedia (2007)
https://wikipedia2007.classicistranieri.com

Static Wikipedia (2006)
https://wikipedia2006.classicistranieri.com

Liber Liber
https://liberliber.classicistranieri.com

ZIM Files for Kiwix
https://zim.classicistranieri.com


Other Websites:

Bach - Goldberg Variations
https://www.goldbergvariations.org

Lazarillo de Tormes
https://www.lazarillodetormes.org

Madame Bovary
https://www.madamebovary.org

Il Fu Mattia Pascal
https://www.mattiapascal.it

The Voice in the Desert
https://www.thevoiceinthedesert.org

Confessione d'un amore fascista
https://www.amorefascista.it

Malinverno
https://www.malinverno.org

Debito formativo
https://www.debitoformativo.it

Adina Spire
https://www.adinaspire.com