>


Web - Amazon

We provide Linux to the World


We support WINRAR [What is this] - [Download .exe file(s) for Windows]

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
SITEMAP
Audiobooks by Valerio Di Stefano: Single Download - Complete Download [TAR] [WIM] [ZIP] [RAR] - Alphabetical Download  [TAR] [WIM] [ZIP] [RAR] - Download Instructions

Make a donation: IBAN: IT36M0708677020000000008016 - BIC/SWIFT:  ICRAITRRU60 - VALERIO DI STEFANO or
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Sikhism - Wikipedia

Sikhism

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́

AYORINDE OLUMUYIWA

SIKHISM

Sikhism jé èsìn tí ó wúlò, kò wà nínú àwon ìgbàgbó kan tàbí àheso òrò lásán, kìí se ti oní wíwá ojúbo àti sárè kiri tàbí oníkanra yogis. Òhun ni ònà ìyè tí a lè ní ìyè lé lórí gégé bí i àwòkóse. Inúkan ni ó dá lé lórí pàtó, kò sì sí ohun tó ju èdá lo tàbí ìtàn ìwásè kan tí ó simi lé, kò gbàgbó nínú èsù tàbí ángélì tàbí èmí ti òrun.

Ó jé èsín gbogbo ènìyàn tí ó lò dì sí ìlànà ìfojú àìtó àti ìsìn wò, kì í se ìgbàgbó tó sókúnkùn, ìgbóràn tó sókúnkùn sí àwon aláse gbogboogbò ni ó lòdi sí, ikú àwon olóye kò ní jé ìyè èmí náà. Ìgbàgbó kò bèrè pèlú ìfura tàbí èèwò. Èsìn yíì jé ìgbàgbó ti ìrètí àti ìmúnínúdùn, bí ó tílè jépé ó tenu mó karma, ó dá síse ìyípadà karima enìkan pèlú ore-òfé tí Guru tàbí Olórun mò, kò jásí àìnírètí àti ìparun. Ó jé èsìn àjùmòse. Ìpinnu tí sangati máa ń kí yèsí ìdánilójú oní òfi ipá (Gurmatta) Guru Gobind singh salub ní àsà ìpéjopò náà. Sikhism, èyí tí ó kéré jùlo nínú àwon èsìn lágbayé. Ó tó ogórùn márùn odún séyìn. Olùdásílè rè, Guru Nanak, ni abí ní ogórùn méfà dín ní ogbòn odún séyìn (1469). Ó tan isé iranse ‘Ek ong Kari tí ó rorùn. A jé òkan, tí adá, nípa se elédà á gbogbo èdá. Eléyìí ni igbàti India yapa nípasè Castes, egbé, èsìn tí ó yapa àti alákatakítí. Kòláàtò pèlú èsìn kankan ó sì bò wò fún gbogbo èsìn. Ó mu dájú wí pé Olórun kan ló wà ó sì pín si orísìí ònà, àti wí pé òtító ni orúko olórun (SatNam).

Àwon alátèlé Hindu àti Mùsùlùmí Guru Nanak ni ó bèrè sí ń pè é ní Sikhs (akékò). Ó kówon láti teríba níwájú Olórun nìkan, àti láti se ara won pò sí tí Guru, ìmólè òtító, tí ó mà ń ní ìtara sí Olórun, nínú ìrírí àìyapa. Nípasè òrò àti àpeere Olùkó èsìn yíì fihàn fún omo èyin rè bí ase ní iríri olórun nínú ara won, mímú won jáde láti inú òkùnkùn wá sínú ìmólè. Olùkó yíì jé onírèlè tí ó ní ìmólè òtító. Ó tako èsìn késìn, ìtàjè rúbo, egbé tíkò gúnrégé àti àìsòótó, ìkòsílè àti àgàbàgebé àti àfipá wá nnkan nípa kíkó orin ti òrun èyí tí ó bá okùn àwon tí ó ń fetísi pàdé. Orin yìí ni a tè, tí a tún ní àwòrán ìbèrè Sikhs. Ìko mímó, tí ó wà pàdà di.

GURU NANAK KONI NIPA ÒNÀ ÌGBÉ AYÉ RÈ

Láti dìde kí òrùn tó tàn, láti we aramó, sísàsàrò nípa orúko olórun àti láti kó orín Guru kí ara wón fi mó ní gbogbo ojó, kí wón sì máa rántí orúko olórún nígbàgbogbo pèlú gbogbo èmí. Amú ìpìlè èsìn yìí le le nípasè Guru Nanak tí ó sì fi ìtara tirè sínú omo èyìn kan, tí ó wá Guru èsìn yìí osi tun ton ìmólè lo sí òdò elòmíràn. Guru yìí ni a mú láti inú gbòngbò òrò ‘Gu’ tí ó túmò sí òkùnkùn tàbí àìní ìmò àti ‘Ru’ tí ó túmò sí ìmólè tàbí ìmò. Guru yíì ní ìmò òtító (olórun).

Òkòòkan Guru mewa yíì ń tóka sí àwòmóni tòrun: Guru Nanak - Ìteríba, Guru Angad-Ìgbóràn, Guru Amar Das-Ìdógba, Guru Ram Das-Guru Arja-Ìséra eni, Guru Hargobind – òdodo, Guru Har Rai-Àánú, Guru Harkrisham-ìwà mímó, Guru Tegh Bahadur-Isim, àti Guru Gobind singh ìláyà bí o ba.


< Static Wikipedia 2008 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -

Static Wikipedia 2007 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -

Static Wikipedia 2006 (no images)

aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu

span style="font-weight: bold;">Our
"Network":



Project Gutenberg

href="https://gutenberg.classicistranieri.com">https://gutenberg.classicistranieri.com



Encyclopaedia Britannica 1911

href="https://encyclopaediabritannica.classicistranieri.com">https://encyclopaediabritannica.classicistranieri.com



Librivox Audiobooks

href="https://librivox.classicistranieri.com">https://librivox.classicistranieri.com



Linux Distributions

https://old.classicistranieri.com



Magnatune (MP3 Music)

href="https://magnatune.classicistranieri.com">https://magnatune.classicistranieri.com



Static Wikipedia (June 2008)

href="https://wikipedia.classicistranieri.com">https://wikipedia.classicistranieri.com



Static Wikipedia (March 2008)

href="https://wikipedia2007.classicistranieri.com/mar2008/">https://wikipedia2007.classicistranieri.com/mar2008/



Static Wikipedia (2007)

href="https://wikipedia2007.classicistranieri.com">https://wikipedia2007.classicistranieri.com



Static Wikipedia (2006)

href="https://wikipedia2006.classicistranieri.com">https://wikipedia2006.classicistranieri.com



Liber Liber

href="https://liberliber.classicistranieri.com">https://liberliber.classicistranieri.com



ZIM Files for Kiwix

https://zim.classicistranieri.com





Other Websites:



Bach - Goldberg Variations

https://www.goldbergvariations.org



Lazarillo de Tormes

https://www.lazarillodetormes.org



Madame Bovary

https://www.madamebovary.org



Il Fu Mattia Pascal

https://www.mattiapascal.it



The Voice in the Desert

https://www.thevoiceinthedesert.org



Confessione d'un amore fascista

https://www.amorefascista.it



Malinverno

https://www.malinverno.org



Debito formativo

https://www.debitoformativo.it



Adina Spire

https://www.adinaspire.com




atOptions = { 'key' : 'e601ada261982ce717a58b61cd5b0eaa', 'format' : 'iframe', 'height' : 60, 'width' : 468, 'params' : {} };

Our "Network":

Project Gutenberg
https://gutenberg.classicistranieri.com

Encyclopaedia Britannica 1911
https://encyclopaediabritannica.classicistranieri.com

Librivox Audiobooks
https://librivox.classicistranieri.com

Linux Distributions
https://old.classicistranieri.com

Magnatune (MP3 Music)
https://magnatune.classicistranieri.com

Static Wikipedia (June 2008)
https://wikipedia.classicistranieri.com

Static Wikipedia (March 2008)
https://wikipedia2007.classicistranieri.com/mar2008/

Static Wikipedia (2007)
https://wikipedia2007.classicistranieri.com

Static Wikipedia (2006)
https://wikipedia2006.classicistranieri.com

Liber Liber
https://liberliber.classicistranieri.com

ZIM Files for Kiwix
https://zim.classicistranieri.com


Other Websites:

Bach - Goldberg Variations
https://www.goldbergvariations.org

Lazarillo de Tormes
https://www.lazarillodetormes.org

Madame Bovary
https://www.madamebovary.org

Il Fu Mattia Pascal
https://www.mattiapascal.it

The Voice in the Desert
https://www.thevoiceinthedesert.org

Confessione d'un amore fascista
https://www.amorefascista.it

Malinverno
https://www.malinverno.org

Debito formativo
https://www.debitoformativo.it

Adina Spire
https://www.adinaspire.com