Web Analytics Made Easy - Statcounter

See also ebooksgratis.com: no banners, no cookies, totally FREE.

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Mysticism - Wikipedia

Mysticism

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́

OWOLABANI JAMES AHISU

OHUN ÌJÌNLÈ TÍ Ó JU OGBÓN ÈNÌYÀN LÁSÁN LO (MYSTICISM)

‘Mysticism’ gégé bí ìwé atúmò èdè Gèésì Collins se sàlàyé: Mysticism is the belief in or experience of a reality surpassing normal human understanding or experience, esp. a reality perceived as essential to the nature of life.

Èyí tí ó túmò ní èdè Yorùbá sí: Èyí túmò sí ìgbàgbó nínú tàbí níní ìrírí nípa ohun tó ju ogbón èníyàn lásán tàbí òye won lo, pàtàkì ni èyí tó se kókó sí ìgbé ayé. Láti inú èdè Greek (mystikos) “an initiate” tí ó túmò sí “ìpìlèsè” ní ìlépa nínú ìdàpò tàbí mímò dájú pèlú mímò sínú nípa nnkan, òótó tí ó gbèyìn ohun ti òrun, òótó ti èmí tàbí Olórun nípa ìrírí tààrà, ogbón inú tàbí àwòsínú; àti ìgbàgbó pé irú ìrírí jé orísun ogbón pàtàkì, òye àti ìmò. Àwon ìgbàgbò tí a ní nínú ìsènbáyé lè jé ohun tó tayo ojú ayé lásán, tàbí ìgbàgbó pé àwon ohun tí àwon ènìyàn n rò tayo ohun tí a lè tojú lásán tàbí ti alákòwe wò. Enikéni tí ó bá wádìí tàbí tí ó wo inú àwon nnkan wònyí jinlè ni à lè pè ní Eni tó mo ohun àsírí tí ó ju ogbón ènìyàn lásán lo.

Ní òpò ìgbà, àwon ohun tí ohun ìjìnlè tí ó ju ogbón ènìyàn lásán lo àti eni tó ní ìgbàgbó nínú àwon ohun náà dale lórí ni bí a se lè dé ipò tàbí kí á wà padà pèlú Olórun tí ó je orí. Àkòrí tí ó gbájúmò nínú ohun ìjìnlè tí ó ju ogbón ènìyàn lásán lo ni pé òun àti eni tó gbà á gbó jé òkan. Ohun tí ó fa ìkópa yìí ní láti rí ìsòkan nínú ìrírí, láti tayo ohun tí a moni mó àti láti jé kí á moni mó gbogbo ohun tí ó wà. Orúko orísìírísìí ní ìsòkan yìí ni láti ìsòrí kan sí òmíràn: Ìjoba tí Òrun (The Kingdom of Heaven), Ìbí ti Èmí (The Birth of the Spirit), Ìjí lojú orun Keta (Third Awakening) Ìdàpò (tí onígbàgbó), abbl.  Ohun tí à n so ni pé ohun tí a pè ní “ohun ìjìnlè tí ó ju ogbón ènìyàn lásán lo jé ohun tí òpòlopò èsìn so mo. Kò sì sí èsìn tí kò ní ohun àsírí tí ó jinlè ju ohun tí enikéni lè tú tàbí mo ìdí rè lo.


aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -