Web Analytics Made Easy - Statcounter

See also ebooksgratis.com: no banners, no cookies, totally FREE.

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Industry - Wikipedia

Industry

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́

INDUSTRY-ISÉ ONÍSÓWÒ

Isé onísòwò jé isé ìtara ni èyíkèyí ìlépa yálà nípa ti ara tàbí ti ìyè, pípinnu ìfojúsí àti ìfarabalè sí isé àti títe ramósé. Isé onísòwò sé òdè sí òlè àti àìfé sisé, nítorí pé isé n san owóo gbèsè, àìfé sisé sí maa n mú gbèsè pòsí.

Isé onísòwò ni èyíkèyí èyà ìmo ònà ìse tí ó gbà púpò làálàá àti okòwòlowó púpò). Isé onísòwò jé ìsé tí ènìyàn nlò agbára, ìyára, ìgbàyànjú àti ìsakun nípa èyíkèyí irú ti gbà si isé. Isé onísòwò n fe owó púpò, amojuto àti ìfarabalè. À tún lè pé ni isé tí o dale lorí ojà tità.

Isé onísowò jé ìdúró sinsin, ìpinnu látì múse sé. O jé akojopo àwon ènìyàn tàbí àwon aajo tí wòn dá owó jo látì fí dá isé náà sílè. Nnkan pàtàkì ní isé onísòwò jé fún gbogbo èká isé. Á máa n ló òrò isé onísòwò fún àwon isé lá kòpò. Tí ilé-isé kan báà pín nínú gbogbo isé, ó jé èyá iloé-isé tí ó tí kó owó isé jo. Àwon èyá ilé-isé onísòwò tí ó wàà ní:

(1) Ilé-isé íwé

(2) ilé-isé efín

(3) Ilé-isé iwò orùn

(4) Ilé-isé áásó

(5) Àwon ilé-isé bàtà

PÀTÀKÌ ISÉ ONÍSÒWÒ


(1) Isé onísòwò jé isé tí ó n pè sè isé fún àwon ènìyàn.

(2) Ó n pè sè ohun èlò fún àwon ènìyàn bí ounje, èro àti àwon ohun ìmúlò.

(3) Wón máa n pè sè ohun a máa áyè deran

(4) ó n mú ìdàgbàsókè bá orò ajé ilè wa.

IPAARI: Isé onísòwò jé nnkan pàtàkì tí gbogbo ilú gbodò ní. Àyíká tí ó bá dára jùlo gbódò ní àwon ilé isé tí ó pò púpò.


aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -