Web Analytics Made Easy - Statcounter

See also ebooksgratis.com: no banners, no cookies, totally FREE.

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Game - Wikipedia

Game

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́

OHUN ÌSERÉ (GAMES)

Ohun ìseré jé ohun eré tí ó máa n wáyé láààrín ènìyàn méjì tàbí jù béè lo. Eré sì lè wáyé láààrin agbo-ilé kan tàbí jù béè lo. Orísìírìsìí àwon ohun ìseré ni ó wà, tí ó sì máa n jé kí ènìyàn tún fún ara rè ní ìsinmi lénu isé. Ara àwon ohun ìseré náà ní e: Àwálè

Àwálè jé ayò olópón tí ó bèrè ní ilè Yorùbá. Yorùbá máa n so wí pé Eré o; la n fomo ayò se tí wón bá fé ta ayò olópón àwon méjì pèlú omo ayò bíi mérín sí inú ihò kòòkan. Nígba tí ayò bá dé òpin eni tí ó bá je omo ayò jù ni ó gbé igbá oró sókè. Àwon olùwòran máa n kí àwon tí ó n tayò ní “mo kóta, mo kópè” eni tí ó gbé igbá oró sókè ni òta, enití kò je púpò ni òpè. Enití ó gbé igbá orókè máa dáhùn wí pé “Òta n jé òpè ò gbodò fohùn”. Àwon olùwòran àti òta máa n fi òpè se yèyé, wón tún le bú u tàbí fi dá àpáàrà.

DÍRÁÀFÙ

Díráàfù jé ayò tí àwon ènìyàn máa n ta láààrin ara won. Irú ayò náà máa n wáyé láààrin ènìyàn méjì. Àwon mìíràn máa n fi ayò náà ta tété. Ibi tí wón ti máa n ta ayò náà dà gégé bíi pákó tí ó ní igun mérin tí ènìyàn kòòkan yóò sì ní ayò ogún ní owó. Nígbà tí ayò náà bá n lo lówó, tí ènìyàn bá dé oba ó le fi oba rè pa oba enìkéjì. Omo kékeré le ta ayò díráàfù, ayò díráàfù jé ayò tí ó gba ogbón púpò, enití kò bá le ronú jinlè, ó seése kí ó má le ta á dáradára. Ayò náà ti rìn dé gbogbo orílè èdè àgbáyé.

Tí a bá ní kí á máa ka àwon ohun ìseré lo, a kò le è kà á, tán ní àsìkò. Sùgbón ìwònyí ni ìwúlò ohun ìseré; ó máa n jé kí ènìyàn rí isé se ní ìgbà gbogbo, nítorí wí pé Yorùbá bò wón ní, “owó tí ó dilè ni èsù máa n bè níse.

Ní ìkádìí, eré síse máa n jé kí ìfé wà láààrin àwon ènìyàn àdúgbò, agbègbè tàbí ìlú kan sí èkejì nítorí wí pé ní ìgbà tí wón bá fi jo n seré papò, wón máa mo ara won dáradára, ìfé tí ó sì gún máa wà ní àárín won.


aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -