Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́
ÀWON ÒWE IḶẸ̀ YORÙBÁ (PROVERBS OF THE YORUBA PEOPLE)
- Ilé oba tójó, ewà ló bù kun.(If you fail once,try again,failure is the preparation of greater things ahead)
- Igi gogoro má gun mi lójú, à t'òkèrè latí wòó.(Be conscious of your actions)
- Bá mi na omo mìi, kò dénu olómo.(Oftentimes people say what they do not mean so thread softly)
- A kìí bá ara eni tan kí á fara eni nítan ya.(When you are given an opportunity,dont misuse or overuse it)
- Àgbà kìí wà lójà, k'órí omo tuntun ó wó.(Where there are elders,things are run smoothly)
- Orí tí yóó gbeni ní gbé aláwo ‘re ko ni.(Your destiny is in your hands)
- Eni tí ó n ko orin tí kò dùn, o ṣa nfeti ara e gbo.(Be careful whatever you do,you might be affecting yourself indirectly)
- Àgbà tí ò bínú ni ọmọ rè n pò jọjọ.(Be slow to anger)
- Kí Ọbìnrin to àtòrìn,Kí Ọkùnrin to àtòrìn,ká wo ẹni tí ó ma lómi léyìn ẹsẹ̀ ju ara won lo.(Competition between people reveals who is stronger)
- Apé kó tó jeun,kò ní jè bàjé.(Delay is not denial)
- Àṣegbé kankan ò sí,àṣepamó lówà.(You can not hide your wrongdoings forever,someday your sins will find you out)
- Bí iró bá lo lógún odún,òtító á padà léebá.
- Iná ogún odún,a máa jó ni lówó felifeli.
- Káronú jinlè ká tó wùwà lóda,ìwà òpònú ni kásekan òún tán,káwá dorí kodò lórí àṣise.