Ẹ̀kọ́ itàn àkọọ́lẹ̀
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́
ÌTÀN
Ìtàn ni èkó ìsèlè oun tí ó kojá, àfojúsùn lórí ìgbé ayé ènìyàn àti tí tí de ìgbé ayé ìsisìnyín. èwè, ìtàn ni onà sísàlàyé àti wíwàdí ìsèlè pàtàkì tí o kojá nínú ìrìn àjò ayé omo èdá, èkó ìsèlè lórí àkókò àti ni ìbámù pèlú omo ènìyàn. Àwon akéèkó ìtàn gégé bi i ise ni à n pè ni Olùsòtàn. Ní Gíríkì ìgbà kan, òrò ìtàn (istoría), túmò sí “ìmò ti a gbà tàbí kójo nípa ìwádìí, ìbéèrè. Nínú ogbón órí yi ni onímò ìjìnlè ti a n pe orúko rè ni Aristotle lo òrò yìí ni èdè rè ITepít ang ZW and Itopí, peritazoa istoria tàbí, ni èdè (Latin, Historia Animalium) A mú àwon àdàko oro ná-na lá ti nú í6twp, history ìtumò -òjògbón, olùjérìí tàbí ajérìí, tàbí onídàjó.
Ìtàn má n wuyì nípa àkójopò síso òtító ohun tí ó kojá. A ti yà eka ìtàn ìpèsè òrò síso yìí. Léèkàn si èwè, ìtàn je sísàlàyé àti wíwádìí ìsèlè tí o kojá ní ibámu pèlú ìrìn àjo ayé ènìyàn; àti, pèlú kí ké kòó gbogbo ìsèlè nínú àkókò ní ìbámu pèlú ènìyàn.
Èwè, ìtàn sáábà má n tóka sí dídá ìsèlè ti o ní ìsèdá agbára tí o má n fónà hàn ni ojó iwájú. Bí àpèère, ìsèlè ti o kojá ìsinsìn yí, àti ojo iwájú pò ma n síwájú ní pa asàfihàn ìtàn. A gbé ìtàn ìsisìnyí ka lè nínú ìrò agbára tí omo ènìyàn fi fún pèlú olùse-ìtàn (hisotorical subjectivity) ní èyí tí o ràn wón lówó nínú àwon ìsèlè àti èyí tó ó rànwónlówó léèkàn-ná-àn láti se àkosílè ati sàlàyé ìsèlè tí o kojá gégé bi ìtàn.
Gbogbo àwon ìtàn tí a rantí àti èyí tí a fi pamó ni àwon ònà kan tí a kò si leè paré jé àkosílè ìtàn (historical record). Àwon ìsèlè ti a rò pé ó tí selè kí á to se àkosílè òrò ní à pè ní asájú-ìtàn (pre-history). Ní nkan bìí ogún ogórùn-ún odun séyìn, a ka ìpín tàbí ìyápa tówà láàrin ìtàn ati asájú ìtàn gégé bíí wáhálà. Àríyànjiyàn dìde nítorí àì ní ìdanilójú àyokúrò ìtàn àwon òlàjú, Wón ti ta ko àwon olùkòtàn ní ìwò-oòrùn fún fífojú sùn nlá lóríi ìwò-oòrùn ayé (Western world).