Ìmọ-ìṣègùn
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́
ÌMÒ ÌSÈGÚN (MEDICINE)
Ìmò tàbí ìwádìí ohun tí n mú àìsàn wá, ìtójú àti ìlòsí ré, tàbí ìdí-lówó àrùn àti àwon ìbàjé sí inú ara Èka. Èkó sayebinsi tí ó rògbàká ìlo àwon ògùn. Óunje ati àwon egbògi múràn. Ó jé ògun tàbí àwon ìtójú sí àìsàn. Nnkan tí ó jé gégé bí àtúnse àrùn ara.
Ìmò ìsègùn jé ìmò àti ònà ogbón nípa sísé ìtójú àti ìmú pàdà-sípò tàbí ìràpdà àlááfià fún ènìyàn nípa àsàrò, ìwádìí ohun tí n mú àìsàn wá àti ìtójú fún àwon aláísàn.
Isé ìmò ìsègún ti ìgbà ìsisìyí hàn púpo, bí èkó ìwòsàn àti gbogbo ìwádìí ìmò ìsègùn fún àwon àìsàn tí won sèsè jade. Ìpínlè ìmò ìsègùn lèní, ní se pèlú èka ìmò ìsègùn, ìwádìí ìsègùn àti egbògi onísègùn, pèlú gbogbo àwon ìwádìí yìí, ìpèníjà tí dé bà àìsàn àti ìpalára.
ITAN NIPA ÌMÒ ÌSÈGÙN
Àwon àpere tàbí àwòrán nínú ìsègùn níi àwon ìlú púpò tí nló adánidá orísun bí ohun eléwé tutu (lílo ègbogi), ìpín eranko àti àwon nnkan tí ó wà nínú erùpè ilè. Ní gbogbo ìlú ìwò-oòrùn, ìmò wàà lòri èsìn àti uana èsìn níi pá tí isègùn. Ní àwon àyíká múràn wón nlò ìmò ìsègùn tí ó tan mo ès`in, àsà irírí àti adánidá orison nínú ìmò ìsègùn.
Àwon èsìn mí gbagbo pé àwon orisa ní èmí, nipe èmí wá nínú ohun gbogbo àti wipe gbogbo ènìyàn ló ní agbára ogùn àti àfòse, èyí ló tún fún won ní agbáara à tí wa ìmò kún ìmò ìsègùn.
Ìlú Géreékìì ni ìmò ìsègùn ti kókó bèrè. Èn ìmò ìsègùn jé ìtèsíwájú tuntun láti dá èyì tí ò pòjú ló nínú ìmò ìsègùn nípa ìlo ìlànà ìmò àti ìsàjo àwon èrí pèlú ìdàgbásòkè àwon òpágun èyí tí ó fónká sí àwon òlùtó jú aláísàn.
ÌLO ÌMÒ ÌSÈGÙN
Èyí ní ìmò bí èní ìpìlè àti ònà tí à n gbà lo àwon ìmò ìsègùn yíì ní àkójopò. Pèlú ogbón inú ati ìdájó ilé-ìwòsàn láti fi mo ìwòsàn tí o tó.
Agbede sí ìmò ìsègùn ni dókítà aláísàn jé, onímò ìsègùn yíí gbódò ní ìbátan pèlú ènìyàn tí ó ní àìsàn láti fi ran lówó. Àwon oníwòsàn miiràn náà má n dá àjòsepò sílè láàrin àwon àti èni tí wón n tójú láti fi mo wan dada.
ÌWÚLÒ ÌMÒ ÌSÈGÙN
Láti se ìwádìí àìsàn
Fún ìtóju àti ìlosí fún àwon aláísàn
Láti mó ohun tí o n fa àìsàn
Fún ìmò nípa lílò àwon ògùn
Láti dín iye àwon tí wón n se àìsàn kù.
IPARI
Gbogbo nnkan tí ó bá ti wà fún ìtójú àìsàn yaálà ní mímu, lílò, pípa ara tàbí fífisùn, ni a npè ní ògùn. Ìmò ìsègùn jé èyà tí ó n se ìgbìmò ìtójú, ìwádìí àti àfíhàn ohun tí ó n fa àìsàn àti ìtójú rè.