Web Analytics Made Easy - Statcounter

See also ebooksgratis.com: no banners, no cookies, totally FREE.

CLASSICISTRANIERI HOME PAGE - YOUTUBE CHANNEL
Privacy Policy Cookie Policy Terms and Conditions
Ìgbàgbọ́ - Wikipedia

Ìgbàgbọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́

ÒGÚNRÁNTÍ DAVID BABÁJÍDÉ

FAITH, HISTORY AND INTEREST IN THE WORD OF GOD

ÌGBÀGBÓ, ÀWON ÌTÀN ÀTIJÓ ÀTI ÌFÉ NÍNÚ ÈKÓ NÍPA OLÓRUN

A ó ri i pé “Ìgbàgbó” máa ń wá nípa ìmò. Ìmò leè wá ní orísirisI ònà; nípa èsìn ààsnà ti ilé àti ìlú ati èrò òbí, ìjo; egbé àti béè. Èyàn tó bá sì jogún ìtàn ayé àtijó nípa bóyá èèkó ní ìmò yíì si. Èyàn le ní èkó nipa ohun kan, léhìn èyí, ìmò. Fún àpeere, èkó nipa Olórun mú ìmò wáá. ìmò nípa rè lákókó ati ohun yókù. Kí ni èyàn fé gbàgbó bí kò bá ní ìmo rè. ohun eyé je leje ń gbéfò. Ìgbàgbó lemú kí èyàn se ohun. Ìmò ni o n fún ni ìgbàgbó yìí. Èkó ni ó sì ń jé kí èyàn jí sí ìmò yí bóyá bíi esìn tí ó le fún ni ní èkó nipa Olórùn. Èkó kékeré àkókó yíò kanlèkùn okán sí ìgbàgbó. Bí èyàn bá síì okàn sí ti Olórun, á gbàgbó yíó sì tèsíwájú. Èkó ìsènbáyé ati ìtàn le jé kí èyàn ji si ìmò náà. Ìmò àkókó sí nipa Olórun yí mú àyípadà dé bá omo éníyàn yó sì fé, léhìn èyí, láti mo èkó nípa ohun tuntun tí ó dé bá ayé rè. Èyí á fun ní ìgbàgbó sí nípa onírurú ohun ti Elédùmarè da àti ohun tí ó le mu dá. Gégé bí ìtan ayé àtijó, orísirísI ònà ni Eledumarè gbà pàdé àwon bàbá wa tí ó jé pé ati ní àkoólè ní orísirísi èsin. àkoólè ní pa nkan ní ó ń fún ní ní ìmò nípa rè. Àkoólè Olórun àti nípa Olórun fún ní ní ímó nípa ti Olórun. Àwon àkoólè yí mú ímó àkókó wá. Bí àwon baba wa se gba àwon àkoólè yí tí wón sì ń gbàgbó ni wón ń ti lé ìrandéran lówó. Ìmò yí ń mú ìgbàgbó wá. Ìgbàgbó àkókó ń mú ìfé nínú èkó àti ìmò nípa Olórun síwájú si wá. Ìfé nínú èkó nípa Olórun sì mú kí ìgbàgbó ènìyàn nínú Olórun pò si. Bí ènìyàn bá sì ní ìgbàgbó, tí kò sì se iyè méjì, ohun rè á máa ja so déédé. Igbàgbó le fún lágbára láti se ohun kan. Ó le jé kí ènìyàn ní èrò, ìse àti ìrísí òtò. Bí Olórun se ń bá àwon baba wa kòòkan pàdé ní ìgba nì, Ó ń bá ènìyàn pàdé ní òní nípa èrò àti èrò sí ìgbàgbó. Nínu èrò yí, ènìyàn ní agbára láti Yàn fún Olórun ní àkóko kan àti ní ìgbà dé ìgbà. Níwájú si èrò yí á jé kí ènìyàn bá ara rè pàdá. Ó sì le ma ara rè ní èmí okàn àti ara.


aa - ab - af - ak - als - am - an - ang - ar - arc - as - ast - av - ay - az - ba - bar - bat_smg - bcl - be - be_x_old - bg - bh - bi - bm - bn - bo - bpy - br - bs - bug - bxr - ca - cbk_zam - cdo - ce - ceb - ch - cho - chr - chy - co - cr - crh - cs - csb - cu - cv - cy - da - de - diq - dsb - dv - dz - ee - el - eml - en - eo - es - et - eu - ext - fa - ff - fi - fiu_vro - fj - fo - fr - frp - fur - fy - ga - gan - gd - gl - glk - gn - got - gu - gv - ha - hak - haw - he - hi - hif - ho - hr - hsb - ht - hu - hy - hz - ia - id - ie - ig - ii - ik - ilo - io - is - it - iu - ja - jbo - jv - ka - kaa - kab - kg - ki - kj - kk - kl - km - kn - ko - kr - ks - ksh - ku - kv - kw - ky - la - lad - lb - lbe - lg - li - lij - lmo - ln - lo - lt - lv - map_bms - mdf - mg - mh - mi - mk - ml - mn - mo - mr - mt - mus - my - myv - mzn - na - nah - nap - nds - nds_nl - ne - new - ng - nl - nn - no - nov - nrm - nv - ny - oc - om - or - os - pa - pag - pam - pap - pdc - pi - pih - pl - pms - ps - pt - qu - quality - rm - rmy - rn - ro - roa_rup - roa_tara - ru - rw - sa - sah - sc - scn - sco - sd - se - sg - sh - si - simple - sk - sl - sm - sn - so - sr - srn - ss - st - stq - su - sv - sw - szl - ta - te - tet - tg - th - ti - tk - tl - tlh - tn - to - tpi - tr - ts - tt - tum - tw - ty - udm - ug - uk - ur - uz - ve - vec - vi - vls - vo - wa - war - wo - wuu - xal - xh - yi - yo - za - zea - zh - zh_classical - zh_min_nan - zh_yue - zu -