Olusegun Agagu
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé-ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Olusegun Kokumo Agagu | |
Gomina Ipinle Ondo
|
|
---|---|
Lori Ipo Lowolowo | |
Assumed office 29 May, 2003 |
|
|
|
Ojoibi | 1948 Ipinle Ondo, Nigeria |
Egbe oloselu | PDP |
Olusegun Kokumo Agagu (born 16 February 1948) je Gomina Ipinle Ondo ni ile Naijiria.
Olúségún Àgàgú Wón bí i ní ferbruary 16, 1948 ní Òkìtìpupa; Ondo State. Ó bèrè ilé-èkó ní St Luké’s Anglican School, Òkìtì pupa ní 1954. Ó tún lo sí Ebenezer Methodist School, Òkè-Àdó, Ìbàdàn ní 1958. Ó tún lo sí Baptist Primacy School, Sabon-gari, Kano. Ó wá parí èkó primary School rè ní Ebenezer African Church School, Ibadan. Léyìn èyí, ó lo sí ìbàdàn Grammar School ní 1961. Léyìn èyí, ó lo sí University Ìbàdàn láti ka Botany. Torí pé ó mo Geology dáadáa, wón fún un ní èkó-òfé Gulf oil láti ka Geology léyìn odún kìíní. Léyìn èkó rè ní University, ó bá Guif oil sisé fún odún méjì kí ó tó wá gbsé sí University of Ìbàdàn gégé bí Assistant Lecturer ní 1972. ó lo kàwé fún oye master rè ní University of Texas láàrin 1973 sí 1974. Ó gbá PhD ní Petroleum Geology ní ní University of Ìbàdàn ní 1978. Ní 1988. ó fi UI sílè, ó sì bèrè síi se òsèlu. Kò pé léyìn èyí, ó di igbákejì Gómínà ìpínlè Ondó. O sì ti bèrè sí í se gómìnà ìpínlè Ondó láti 2003 títí di ìgbà tí a n kòwé yòí ní 2008.
|
|||
---|---|---|---|
Abia: Theodore Orji |
Delta: Emmanuel Uduaghan |
Kano: Ibrahim Shekarau |
Ondo: Olusegun Agagu |